Olorun Ase Oro C&s Church Agbojesu Branch

Olorun Ase Oro C&s Church Agbojesu Branch Olorun Ase Oro C&s Church Agbojesu Branch was Found by Prophet Olayiwola Ogedengbe an annointed man

01/01/2022

Happy🌠🌠🌠🌠 New 🌠🌠🌠Year🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠🌠✨as we enter this new year 2022 with Joy so shall we end it with great Happiness

17/11/2021

To all the members of this group
I pray" You shall not lack in Jesus name,and
May the Doors of Opportunities to be Successful in life shall be Open for you in Jesus name,
You shall not beg to Survive in the Mighty name of Jesus...... Wish you Merry Christmas in Advance💓💓💓

Iwo ti eniyan tiku ni isoju ë ti elomii tun ti see ori ire ni igba kan na ni oju rë ni mo n bawi..ti o kan mo wipe OBA A...
10/11/2021

Iwo ti eniyan tiku ni isoju ë ti elomii tun ti see ori ire ni igba kan na ni oju rë ni mo n bawi..ti o kan mo wipe OBA ASEYIOWU ni OLORUN wa ti a n sin..mo gba ladura lowurö yii""gbogbo ireti rë ni rere ninu odun yii Lorukö Jesu OLORUN ko mu wa si imuse..nibi ti awön kan nsunkun löwo nibë ni awön kan ndunu Lorukö Jesu laarin awön olori ire eniyan to ndunu löwo,,ORUN ko ka ë yë"" ...Laarin awön to wa nsunkun abi to.ma sunkun lodun yii ati lodun to n bö ORUN ko yö ë kuro...ësë to ma mu ki Ibinu OLORUN ru sori rë tömotömo Lorukö Jesu OLORUN ko dari ësë rë ji ë...oo ni daamu lasan..ASE lo ri ogo lo Olorun a fi lë ë lowö...jesu Oluwa wa

Hello Everyone 😊Happy New Month!!!  Our Annual ARK OF CONVENANT Anniversary comes up on the 3rd of October next Month..V...
01/09/2021

Hello Everyone 😊Happy New Month!!!
Our Annual ARK OF CONVENANT Anniversary comes up on the 3rd of October next Month..Vigil start on the 10th September and it ends on the 30th while the Praise night is on the 1st of October..
Event: ASE ORO C&S AGBOJESU CONFERENCE
Date:Night vigil starts on the 10th of this Month...
Time:service starts by 10:00a.m
ERI ASE ORO DAY:3-10-2021
Venue:Back of Baalë House,Awofe Street, Alasia Bus stop ijoko Sango ota,Ogun State, Nigeria..
Thanks for taking your time!!
OBA ERI 🚩A GBE WA OOOOO!!!!

Lórukō Jësu Aanu nla ti ë o fökan si ninu osu yii to ma fi ni Testimony Ayö Lórukō Jësu Aanu naa ko to yin löwo...
08/08/2021

Lórukō Jësu Aanu nla ti ë o fökan si ninu osu yii to ma fi ni Testimony Ayö Lórukō Jësu Aanu naa ko to yin löwo...

12/07/2021

Lórukō Jësu Ori wa o ni gbabode..
Mo ni afefe aisan o ni kolu wa..
Ëmi Ölorun o ni fi wa sile..Jësu Oluwa wa

07/06/2021

Mo gbadura fun yin Lórukō OBA ERI;Ogo nla to aiye yio fi ro pë ë ti seso Lórukō Jësu ERI ko gbe lëyin löwö....

Mo sö pëlu Asë Eri, gbôgbo ona ti öta ti di mö yin Lórukō Olorun Oba Eri Ase Örö,awön Malaika to n la öna fun ERI Lórukō...
09/05/2021

Mo sö pëlu Asë Eri, gbôgbo ona ti öta ti di mö yin Lórukō Olorun Oba Eri Ase Örö,awön Malaika to n la öna fun ERI Lórukō Jësu ki wön Lana fun yin..ona ogo,ona igbega,ona Aanu nla ko bërë sii la fun yin

09/05/2021

Ni Öjö Isinmi Iserere logo toni; a o ni lö löwö òfo,a ò ni gberè airigba....

27/04/2021

Një niti Ëbun Ëmi, Ara;Emi ko fë ki ëyin ki o jë ÒPÈ"

18/04/2021

Moki yin ku Öjö Isinmi nla toni.. Lórukō Jësu Ëmi Ölorun ko ni fiwa silë...

Address

Ijoko

Telephone

+2348032354414

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorun Ase Oro C&s Church Agbojesu Branch posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share