13/10/2021
OSO GIDI TO DAJU Odindi eyele 2, afara oyin, ileke iyun, ewe omisinmisin onitakun, Sisere,, ao mu okan ninu eyele yi ao fi kan ori wa ao se adura si dada ao wa san mole lekan na koku, ao wa ju sinu agbada tati gbe kano, ao Jo pelu awon ewe yi, yato si ileke iyun yen ao lo ohun loto ni, ti abati jo tan alo kunna ao da ileke ti aloyen mo, ao wa polose, ao ti ran a*o funfun ni apo kan, ao ko ose yi sinure ao ja eyele to Ku ao ro ejere lori oaeyi ao wa ti ori re bonu oseyi ao so lenu aowa gbeko enu ona abawole loke fun 14 days kato ma buwe, pelu ofore
Gbolohun: Eyibieyi awo ataye baye, Atambata awo ode orun, Ogbonla sori jagajigi, Awon lodifa fun Orunmila ni igba ton ti ikole orunvbo wavsi Ikole aye, ode ibode orun ataye, onibode bere lowore wipe nibo lonlo, orunmila ni ounlo sode ayeni, onibode dalohun wipe oso tilo, aje tilo, Omo araye abi oju perekete ti kin je ki oniwagun wa, orunmila babinu pada s**o olodumare, olodumare ni kolowa eyin oku ila, afara oyin, oni kofi se IFA koma fiwe oni oso aye yio ma sin o, aje aye yio ma sin o, emi lagbaja moti wa eyin oku ila afara oyin adidi eyele motifi se ifa motifiwe loni, koso aye masin mi aje aye masin mi Alfa ati Woli aye e t c ki won ma sinmi, tori omisinminsin kin se be tire komadun. IKILO =AKO GBODO WO INU APO OSE YI RARA TAA FI LOTAN.
Owale fun tita iwo ti obanife si 08095509091